Awon Arun Okan

Oludanileko : Isa Akindele Solahudeen

Sise atunyewo: Hamid Yusuf

Ọ̀rọ̀ ṣókí

1- Ibanisoro yii se afihan orisi ona meta ti Okan pin si, bee si ni Olubanisoro je ki a mo awon orisi arun ti o ma nse Okan.
2- Alaye ni afikun lori okan ti o nse aare ati ohun ti o je iwosan fun un. Iwosan ti o si dara julo ni nini igbagbo ti o peye ninu Olohun Allah ati mima ka Alukurani Alaponle ni gbogbo igba.

Download
Ko idasọrọ si alamojuto oju ewe yii