Die Ninu Awon Ewa Islam

Awon oludanileko : Hamid Yusuf - Abdul-jeleel Alagufon

Sise atunyewo: Hamid Yusuf

Ọ̀rọ̀ ṣókí

1- Oro waye ninu waasi yi lori Itumo gbolohun Islam ati alaye bi o se je wipe ijosin Ojise Olohun, iwa re ati ise re je apejuwe ti o daju fun itumo paapaa esin Islam. Oro si tun waye lori bi ’waayi’ se maa n so kale fun Ojise Olohun.
2- Ninu awon Ewa esin Islam ti oniwaasi menu ba ninu apa keji yi ni bi Islam se je esin gbogbo abgaye, ti o tun je esin ti o pe perepere, bakannaa ti o si je esin ti o rorun julo.

Download
Ko idasọrọ si alamojuto oju ewe yii