Awọn Aaye ti a kọ fun wa lati kirun nibẹ

Oludanileko : Sharafuddeen Gbadebọ Raji

Sise atunyewo: Hamid Yusuf

Ọ̀rọ̀ ṣókí

Alaye nipa awon aaye ti ko leto ki Musulumi ki irun nibe gege bii ite oku ati ile egbin.

Download
Ko idasọrọ si alamojuto oju ewe yii