Iwọ Aladugbo
Oludanileko : Abdur Rahman Muhammadul Awwal
Sise atunyewo: Hamid Yusuf
Ọ̀rọ̀ ṣókí
1- Idanilẹkọ yi sọ nipa itumọ aladugbo pẹlu itọka rẹ lati inu Alukurani, bakannaa ọrọ tun waye lori diẹ ninu awọn iwọ aladugbo gẹgẹ bii ki Musulumi jẹ ki ọkan aladugbo rẹ balẹ, ki o ma je ki suta tabi aburu wa lati ọwọ rẹ si aladugbo rẹ.
2- Itẹsiwaju alaye lori awọn iwọ aladugbo, ọrọ waye nibẹ wipe ninu awọn iwọ aladugbo yoku ni: didaabobo o, sise daradara si i, sise amumọra fun aburu ọwọ rẹ ati bẹẹbẹẹ lọ.
- 1
MP3 26 MB 2019-05-02
- 2
MP3 26.2 MB 2019-05-02
Àwọn ìsọ̀rí ti ìmọ̀: