Awọn Isẹ ti Ẹsan wọn yoo sẹku fun Musulumi lẹyin Iku
Oludanileko : Abdur Rahman Muhammadul Awwal
Sise atunyewo: Hamid Yusuf
Ọ̀rọ̀ ṣókí
Idanilẹkọ yii da lori awọn Isẹ ti ẹsan wọn maa nbe gbere lẹyin iku pẹlu apejuwe lati inu ẹgbawa hadisi.
- 1
Awọn Isẹ ti Ẹsan wọn yoo sẹku fun Musulumi lẹyin Iku
MP3 25.3 MB 2019-05-02
Àwọn ìsọ̀rí ti ìmọ̀: