-
Qomorudeen Yunus "Onka awon ohun amulo : 39"
Ọ̀rọ̀ ṣókí :O je akekojade ni ile eko giga Al-imam University ni ilu Riyadh, o si je okan ninu awon onimimo ni oju ona sunna ni ile Yoruba. O tun je oludasile ati olori Jamiyyatul Idaaya ni adugbo Olambe ni ipinle Ogun. O ni igbiyanju ti o po ni oju ona Olohun ati ipepe si esin Islam.