-
Sharafuddeen Gbadebọ Raji "Onka awon ohun amulo : 46"
Ọ̀rọ̀ ṣókí :Sheikh Sharafudeen Gbadebo: O je okan ninu awon olukekojade ni ile eko Islamic University ni ilu Madina, O ni igbiyanju lori titu awon iwe esin si ede Yoruba nigbati o n keko ni ilu Madina. O si je okan ninu awon olupepe si oju ona Olohun ni ilana Sunna ni ile Yoruba.