Pataki Adua

Awon oludanileko : Qomorudeen Yunus - Saeed Jumua

Sise atunyewo: Saeed Jumua

Ọ̀rọ̀ ṣókí

Ibanisoro yi da lori adua ati pataki re. Adua ni ohun ti o je oranyan fun Musulumi lati maa se nigbakiigba ti o ba nfe nkan, ki o si doju adua naa ko Olohun re, ki o mase pe elomiran ayafi Oun.

Download
Ko idasọrọ si alamojuto oju ewe yii