Awọn Ẹkọ ti o nbẹ fun jijẹ ati mimu

Ọ̀rọ̀ ṣókí

1- Ninu abala yi ọrọ waye lori wipe ounjẹ ti Ọlọhun Allah pese fun wa idẹra ni o jẹ ati alaye idi ti o fi jẹ idẹra. Bakannaa awọn nkan ti o dara pupọ lati se akiyesi rẹ nigba ti a ba fẹ jẹ ounjẹ.
2- Abala yii jẹ itẹsiwaju alaye lori awọn ẹkọ ti o rọ mọ jijẹ ati mimu, ẹkunrẹrẹ alaye si waye lori awọn nkan ti o dara pupọ lati jina si ni asiko ti a ba fẹ jẹ tabi mu.

Download
Ko idasọrọ si alamojuto oju ewe yii