Ninu Awọn Apẹẹrẹ Ọjọ Ikẹhin - Jijade Masiihu Dajjaal

Ọ̀rọ̀ ṣókí

1 - Ọrọ nipa Masiihu Dajjaal gẹgẹ bi Ojisẹ Olọhun [Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki o maa ba a]
ti se apejuwe ati awọn iroyin rẹ fun wa.
2 - Agbegbe yii pese idahun si awọn ibeere yii: Se Masiihu Dajjaal nsẹmi lọwọ lọwọ, Njẹ yoo bimọ, ilu wo ni yoo ti jade, ati wipe awọn ilu wo ni ko nii de.

Download
Ko idasọrọ si alamojuto oju ewe yii