Itumo Ki Oko o Ko Iyawo re Sile ati Awon Aburu ti o Wa Nibe
Oludanileko : Abdul-jeleel Alagufon
Sise atunyewo: Hamid Yusuf
Ọ̀rọ̀ ṣókí
Ibanisoro yi mu idahun wa lori awon ibeere wonyi: Kinni itumo tolaaki ati itumo Khulkhu, agbara wo ni ile ejo ni lati se onpinya laarin oko ati aya atipe kinni aburu ti o wa nibi ki onpinya sele laarin oko ati aya.
- 1
Itumo Ki Oko o Ko Iyawo re Sile ati Awon Aburu ti o Wa Nibe
MP3 35.3 MB 2019-05-02
Àwọn ìsọ̀rí ti ìmọ̀: