Alaye nipa Irun Odun Mejeeji ninu tira Buluugul-maraam
Oludanileko : Sharafuddeen Gbadebọ Raji
Sise atunyewo: Hamid Yusuf
Ọ̀rọ̀ ṣókí
1- Alaye lori Irun Ọdun mejeeji ati awọn ofin ti o rọ mọ aaye ikirun pẹlu awọn imura ti wọn fẹ ki a mu fun Irun ọdun.
3- Idanileko ni apa yi da lori awọn ẹwa khutuba Ojise Olohun- ike ati ola Olohun ki o maa ba a- ni ọjọ odun ati tita koko ọrọ lori wipe se o maa ngbe minbari lọ si aaye ikirun ni tabi wọn mọ pa si ibẹ.
- 1
Alaye nipa Irun Odun Mejeeji ninu tira Buluugul-maraam -1
MP3 13.4 MB 2019-05-02
- 2
Alaye nipa Irun Odun Mejeeji ninu tira Buluugul-maraam -3
MP3 15.4 MB 2019-05-02
Àwọn ìsọ̀rí ti ìmọ̀: