Ọla ti o nbẹ fun Aluwala ati bi a ti se nse e
Oludanileko : Abdur Rahman Muhammadul Awwal
Sise atunyewo: Hamid Yusuf
Ọ̀rọ̀ ṣókí
Idanilẹkọ yii da lori alaye bi a se nse aluwala ati awọn ẹsan (ọla) ti o nbẹ fun aluwala sise, bakannaa ọrọ nipa awọn ohun ti o nsọ aluwala di ọranyan fun musulumi.
- 1
Ọla ti o nbẹ fun Aluwala ati bi a ti se nse e
MP3 24.6 MB 2019-05-02
Àwọn ìsọ̀rí ti ìmọ̀: