Ọranyan titẹle Asẹ Ọlọhun Allah ati Asẹ Ojisẹ
Oludanileko : Abdur Rahman Muhammadul Awwal
Sise atunyewo: Hamid Yusuf
Ọ̀rọ̀ ṣókí
Idanilẹkọ yi da lori wipe titẹle asẹ Ọlọhun ati asẹ Ojisẹ Rẹ (ike ati ola Ọlọhun ki o maa ba a) ni ojulowo ẹsin. Alaye si tun waye nipa wipe sise ọjọ ibi Anọbi (Maoludi Nabiyi) ko ba ofin ẹsin Islam mu pelu awọn ẹri.
- 1
Ọranyan titẹle Asẹ Ọlọhun Allah ati Asẹ Ojisẹ
MP3 29 MB 2019-05-02
Àwọn ìsọ̀rí ti ìmọ̀: