Àwọn ìsọ̀rí ti ìmọ̀

معلومات المواد باللغة العربية

Ọlá ti n bẹ fún ìwà

Onka awon ohun amulo: 4

  • Yoruba

    MP3

    Oludanileko : Abdur Rahman Muhammadul Awwal Sise atunyewo : Hamid Yusuf

    Alaye ohun ti o njẹ gba-fi-pamọ lati inu Alukuraani ati Sunnah ati alaye gbogbo ohun ti o ko si abẹ gbafipamọ.

  • Yoruba

    MP3

    Oludanileko : Abdur Rahman Muhammadul Awwal Sise atunyewo : Hamid Yusuf

    1- Idanilẹkọ yi sọ nipa itumọ aladugbo pẹlu itọka rẹ lati inu Alukurani, bakannaa ọrọ tun waye lori diẹ ninu awọn iwọ aladugbo gẹgẹ bii ki Musulumi jẹ ki ọkan aladugbo rẹ balẹ, ki o ma je ki suta tabi aburu wa lati ọwọ rẹ si aladugbo rẹ. 2- Itẹsiwaju alaye lori awọn iwọ aladugbo, ọrọ waye nibẹ wipe ninu awọn iwọ aladugbo yoku ni: didaabobo o, sise daradara si i, sise amumọra fun aburu ọwọ rẹ ati bẹẹbẹẹ lọ.

  • Yoruba

    MP3

    Oludanileko : Abdur Rahman Muhammadul Awwal Sise atunyewo : Hamid Yusuf

    1- Alaye wa ninu idanilẹkọ yii lori: (1) Itumọ ikẹ ati aanu gẹgẹ bi awọn onimimọ ẹsin se se alaye rẹ. (2) Diẹ ninu awọn agbegbe ti ikẹ ati aanu ti gbodo maa waye gẹgẹ bii ki olori se ikẹ fun awọn ọmọlẹyin rẹ ati sise aanu fun awọn ọmọde. 2- Alaye waye ni apa yii lori: (1) Awọn agbegbe yoku ti o ti yẹ ki eniyan ti maa se aanu. (2) Awọn anfaani ti o wa ninu aanu sise. (3) Sise daradara pẹlu awọn ẹranko naa wa lara aanu sise.

  • Yoruba

    MP3

    Oludanileko : Abdul-jeleel Alagufon Sise atunyewo : Hamid Yusuf

    Oniwaasi so wipe awon majemu meta kan wa fun jije eni Olohun (i) Ki eniyan so asepo laarin ara re ati Olohun re (ii) Ki o so asepo laarin oun ati emi ara re (iii) Ki o so asepo laarin oun ati awujo re.