Àwọn ìsọ̀rí ti ìmọ̀

معلومات المواد باللغة العربية

Àwọn dáadáa ati ọla ti n bẹ fún Islam

Onka awon ohun amulo: 3

  • Yoruba

    MP3

    Oludanileko : Hamid Yusuf Oludanileko : Abdul-jeleel Alagufon Sise atunyewo : Hamid Yusuf

    1- Oro waye ninu waasi yi lori Itumo gbolohun Islam ati alaye bi o se je wipe ijosin Ojise Olohun, iwa re ati ise re je apejuwe ti o daju fun itumo paapaa esin Islam. Oro si tun waye lori bi ’waayi’ se maa n so kale fun Ojise Olohun. 2- Ninu awon Ewa esin Islam ti oniwaasi menu ba ninu apa keji yi ni bi Islam se je esin gbogbo abgaye, ti o tun je esin ti o pe perepere, bakannaa ti o si je esin ti o rorun julo.

  • Yoruba

    MP3

    Oludanileko : Abdur Rahman Muhammadul Awwal Sise atunyewo : Hamid Yusuf

    Alaye ni ẹkunrẹrẹ waye ninu idanilẹkọ yii lori ẹkọ ti o rọ mọ gbogbo ẹni ti n se isẹ sin eniyan.

  • Yoruba

    MP3

    Oludanileko : Abdur Rahman Muhammadul Awwal Sise atunyewo : Hamid Yusuf

    1- Alaye wa ninu idanilẹkọ yii lori: (1) Itumọ ikẹ ati aanu gẹgẹ bi awọn onimimọ ẹsin se se alaye rẹ. (2) Diẹ ninu awọn agbegbe ti ikẹ ati aanu ti gbodo maa waye gẹgẹ bii ki olori se ikẹ fun awọn ọmọlẹyin rẹ ati sise aanu fun awọn ọmọde. 2- Alaye waye ni apa yii lori: (1) Awọn agbegbe yoku ti o ti yẹ ki eniyan ti maa se aanu. (2) Awọn anfaani ti o wa ninu aanu sise. (3) Sise daradara pẹlu awọn ẹranko naa wa lara aanu sise.