Awọn Ọna ti o ba Ẹsin Islam mu fun Isọ Ọlọhun ati Aabo Rẹ

Ọ̀rọ̀ ṣókí

Idanilẹkọ yii da lori awọn ọna ti musulumi fi le wa isọ Ọlọhun ati aabo Rẹ gẹgẹ bii: Jijẹ eso dabidun ‘ajiwa, sise aluwala loore koore, mima ki irun Fajri ni jama’a, mima ki irun oru, ati bẹẹ bẹẹ lọ.

Download
Ko idasọrọ si alamojuto oju ewe yii