Àwọn ìsọ̀rí ti ìmọ̀

معلومات المواد باللغة العربية

Àwọn ẹgbẹ́ inú Islam

Onka awon ohun amulo: 2

  • Yoruba

    MP3

    Oludanileko : Abdur Rahman Muhammadul Awwal Sise atunyewo : Hamid Yusuf

    1- Alaye nipa awọn ijọ ti njẹ Shii’ah ati wipe ki ni adisọkan wọn nipa Ọlọhun ati si Alukuraani 2- Igbagbọ ijọ Shii’ah si awọn Sahabe ati ipo ti wọn gbe awọn asiwaju wọn si 3- Alaye diẹ ninu awọn adisọkan wọn gẹgẹ bii:- Tukyah, Muta’h. Ti oludanilẹkọ si tun jẹ ki a mọ adisọkan si ijọ Ahalu sunnah wal jamaa’ah

  • Yoruba

    MP3

    Oludanileko : Abdur-rosheed Ballo Oluajo Sise atunyewo : Rafiu Adisa Bello

    Awon janmoo Islam ti o wa ni awujo ni anfaani pupo, awon ni won nse itoju awon omo Musulumi ti won ko je ki opolopo won ti sina tabi di keferi, won maa nse alaye esin fun awon omode ati odo ati agbalagba, bibe won ni awujo si je amin isokan fun awa Musulumi. Sugbon apa kan ninu awon janmoo yi ni awon aleebu kookan gege bii ki a gba wipe olori janmoo ko le se asise ati wipe janmoo ti a ba wa ninu re nikan ni ona sunna ti o dara julo, irufe awon nkan yii ni olubanisoro menu ba ninu waasi yi.