- Al-Quraani Alaponle
- Sunna
- Ìmọ̀ Akiida
- Ìmọ̀ Taohiid àti ìpín rẹ
- Ìjọsìn ati ìran rẹ̀
- Islam
- Ìgbàgbọ́ ati awọn origun rẹ̀
- Àwọn ọrọ nípa ìgbàgbọ́
- Ṣíṣe dáadáa
- Ṣíṣe aigbagbọ
- Ìwà munaafiki
- Ẹbọ àti ewu rẹ̀
- Àwọn adadaalẹ ati ìran wọn àti àpèjúwe wọn
- Àwọn sàábé ati awọn aráalé anọbi Muhammad
- Wíwá àtẹ̀gùn
- Jijẹ wòlíì ati awọn iṣẹ ìyanu àwọn wòlíì
- Àwọn alujannu
- Ìsòtítọ́ àti ìbọ́pá-bọ́sẹ̀ ati awọn ìdájọ́ rẹ.
- Àwọn ahlus sunna wal jamaa'at
- Àwọn ẹ̀sìn
- Àwọn ẹgbẹ́
- Àwọn ẹgbẹ́ inú Islam
- Àwọn ọ̀nà ìròrí ayé òde òní
- Agbọye ẹsin
- Àwọn ìjọsìn
- Imọra ati awọn idajọ rẹ
- Irun
- Òkú
- Sàká
- Aawẹ
- Hajj ati Umra
- Àwọn idajọ khutuba Jímọ̀
- Irun aláìsàn
- Irun arìnrìn-àjò
- Irun ìpayà
- Biba ara ẹni lo
- Ìbúra àti ìlérí
- Ẹbí
- Ìgbéyàwó
- Kíkọ obìnrin
- Kíkọ obìnrin tí ó bá sunna mu ati Kíkọ obìnrin ti ko ba sunna mu
- Kíkọ obìnrin ti a lè gbà padà ati èyí tí a o lè gbà padà
- Àsìkò tí obìnrin ti òun àti ọkọ rẹ pínyà fi máa kóra ró
- Kí ọkọ àti ìyàwó jọ gbé ara wọn ṣẹ́ èpè
- Fifi ẹ̀yìn ìyàwó ẹni wé ti ìyá ẹni
- Bibura pe eeyan ko nii sunmọ ìyàwó rẹ̀
- Kí ìyàwó kọ ọkọ silẹ
- Gbígba obìnrin tí a kọ̀ padà
- Fífún lọ́yàn
- Títọ́jú
- Ìnáwó
- Aṣọ àti ọ̀ṣọ́
- Fàájì àti àríyá
- Àwùjọ Musulumi
- Ọrọ tí ó jẹ mọ́ ọ̀dọ́
- Ọrọ nipa àwọn obìnrin
- Ọrọ tí ó jẹ mọ́ ọmọdé
- Ìwòsàn àti lílo oògùn àti rukiya ti o bá sheria mu
- Àwọn oúnjẹ ati awọn nǹkan mímu
- Dídá ọ̀ràn
- Ìdájọ́
- Jijagun ẹ̀sìn
- Agbọye awọn àlámọ̀rí tuntun ti o ṣẹ̀ṣẹ̀ ṣẹlẹ̀ ti o n bukata si idajọ ẹsin
- Agbọye ẹ̀sìn àwọn to kéré jù
- Òṣèlú ti shẹria
- Awọn ojú ìwòye nípa agbọye ẹ̀sìn
- Fatawa
- Awọn ipilẹ (ìlànà) agbọye ẹsin.
- Àwọn tira agbọye ẹsin
- Àwọn ìjọsìn
- Awọn iwa rere
- Ede Larubawa
- Pipepe sínú Islam
- Ohun ti o jẹ dandan fun Musulumi
- Awọn ọrọ ti maa n jẹ ki ọkàn ó rọ̀ àti àwọn wáàsí.
- Pipaṣẹ dáadáa ati kikọ kuro nibi ibajẹ.
- Ipò ti pipepe si ti Ọlọhun wa
Fonran ohun
Onka awon ohun amulo: 145
- Yoruba Oludanileko : Abdur Rahman Muhammadul Awwal Sise atunyewo : Hamid Yusuf
Alaye lori awọn majẹmu wiwa tituuba lọsi ọdọ Ọlọhun
- Yoruba Oludanileko : Abdur Rahman Muhammadul Awwal Sise atunyewo : Hamid Yusuf
Ninu idanilẹkọ yii: (1) Pataki suuru sise. (2) Ọna maarun ti suuru pin si. (3) Ẹsan rere ti nbẹ nibi suuru sise.
- Yoruba Oludanileko : Abdur Rahman Muhammadul Awwal Sise atunyewo : Hamid Yusuf
Idajọ ti o rọ mọ ọsọ obinrin sise pẹlu ojupọnna ti obinrin le gba se ọsọ ninu Islam
- Yoruba Oludanileko : Abdur Rahman Muhammadul Awwal Sise atunyewo : Hamid Yusuf
Idanilẹkọ yii da lori awọn Iwa Abiyì ti a le kọ ẹkọ rẹ lati ara Anọbi Muhammad [Ikẹ ati ola Ọlọhun ki o maa ba a]
- Yoruba Oludanileko : Abdur Rahman Muhammadul Awwal Sise atunyewo : Hamid Yusuf
Pataki irun kiki ati wipe ohun ni akọkọ ohun ti Musulumi yoo se isiro rẹ ni ọjọ ajinde. Diẹ ninu awọn aisedeede naa gẹgẹ bii: aifarabalẹ, wiwo ọtun wosi lori irun ati bẹẹbẹẹ lọ.
- Yoruba Oludanileko : Abdur Rahman Muhammadul Awwal Sise atunyewo : Hamid Yusuf
Diẹ ninu awọn okunfa ipanle, janduku ati aigbọran ti awọn ọmọ ya kalẹ si awujọ. Itẹsiwaju ninu alaye awọn okunfa ipanle pẹlu awọn ọna abayọ si awọn iwa buburu yii.
- Yoruba Oludanileko : Abdur Rahman Muhammadul Awwal Sise atunyewo : Hamid Yusuf
Alaye ohun ti o njẹ ẹran ikomọjade ati awọn ẹri ti o tọka si i ninu Sunna. Alaye awọn idajọ ẹran ikomọjade pẹlu sisọ awọn majẹmu ti o rọ mọ ọ. Abala yii ni oludanilẹkọ ti jẹ ki a mọ boya a le se ẹran ikomọjade ni ọbẹ, ki a pe awọn eniyan waa jẹ ẹ, tabi dandan ni ki a pin in ni tutu?
- Yoruba Oludanileko : Abdur Rahman Muhammadul Awwal Sise atunyewo : Hamid Yusuf
1- Idanilẹkọ yii sọ nipa oniranran apejuwe nipa ibugbe Alujannah gẹgẹ bi awọn apejuwe yii se wa lati inu Alukuraani ati Sunnah Ojisẹ Ọlọhun. 2- Alaye lori awọn isẹ ti o maa nse okunfa wiwọ Alujannah gẹgẹ bi Ọlọhun ti se se iroyin rẹ lati inu Alukuraani ati Sunna.
- Yoruba Oludanileko : Abdur Rahman Muhammadul Awwal Sise atunyewo : Hamid Yusuf
1- Idanilẹkọ ni agbegbe yii sọ awọn ayọka Alukuraani ati ẹgbawa hadisi ti nse apejuwe bi Ina se ri. 2- Alaye awọn okunfa ti o maa nmu eniyan wọ Ina, awọn okunfa yii pin si meji: (1) Okunfa ti o maa nmu eniyan bẹ ninu Ina lọ gbere, (2) okunfa ti o maa nmu Musulumi bẹ ninu Ina fun igba diẹ.
- Yoruba Oludanileko : Abdur Rahman Muhammadul Awwal Sise atunyewo : Hamid Yusuf
Idanilẹkọ yii se alaye ọrọ awọn onimimọ ti o da lori igba ti o yẹ ki a maa ki Irun Jimọh, ni idahun si asigbọye ẹsin eyi ti o n waye lati ọwọ ikọ awọn ọdọ Musulumi kan ti wọn ngbe Irun Jimọh duro ni aago mẹsan awurọ.
- Yoruba Oludanileko : Abdur Rahman Muhammadul Awwal Sise atunyewo : Hamid Yusuf
Alaye ohun ti o njẹ gba-fi-pamọ lati inu Alukuraani ati Sunnah ati alaye gbogbo ohun ti o ko si abẹ gbafipamọ.
- Yoruba Oludanileko : Abdur Rahman Muhammadul Awwal Sise atunyewo : Hamid Yusuf
Alaye ni ẹkunrẹrẹ waye ninu idanilẹkọ yii lori ẹkọ ti o rọ mọ gbogbo ẹni ti n se isẹ sin eniyan.
- Yoruba Oludanileko : Abdur Rahman Muhammadul Awwal Sise atunyewo : Hamid Yusuf
1- Ninu idanilẹkọ yii ọrọ waye nipa awọn ojuse ti Islam fẹ fun ẹni ti ko ni alaafia lati se ati awọn ojuse ti Ẹsin fẹ fun awọn olutọju rẹ ki wọn se fun un. 2- Itẹsiwaju ninu alaye awọn ojuse ti Islam fẹ fun awọn olutọju alaare lati se nigbati o ba npọkaka iku. 3- Ni abala yii, alaye ti o kun waye nipa awọn ojuse ti Islam fẹ ki a se nigba ti oku ba ku tan.
- Yoruba Oludanileko : Abdur Rahman Muhammadul Awwal Sise atunyewo : Hamid Yusuf
Idanilẹkọ yi sọ nipa idajọ ki eniyan se ounjẹ lati fi ko awọn eniyan lẹnu jọ ati bẹẹ bẹẹ lọ ninu awọn ẹkọ ti o rọ mọ apejẹ sibi igbeyawo (walimọtu- nikahi).
- Yoruba Oludanileko : Abdur Rahman Muhammadul Awwal Sise atunyewo : Hamid Yusuf
1- Ninu abala yi ọrọ waye lori awọn nkan ti o ye ki arinrinajo se ki o to bẹrẹ irinajo rẹ. 2- Ninu abala yi ọrọ waye lẹkunrẹrẹ lori awọn ẹkọ ti o yẹ ki arinrinajo maa mu lo ni asiko ti ba nse irinajo rẹ.
- Yoruba Oludanileko : Abdur Rahman Muhammadul Awwal Sise atunyewo : Hamid Yusuf
1- Ninu abala yi ọrọ waye lori wipe ounjẹ ti Ọlọhun Allah pese fun wa idẹra ni o jẹ ati alaye idi ti o fi jẹ idẹra. Bakannaa awọn nkan ti o dara pupọ lati se akiyesi rẹ nigba ti a ba fẹ jẹ ounjẹ. 2- Abala yii jẹ itẹsiwaju alaye lori awọn ẹkọ ti o rọ mọ jijẹ ati mimu, ẹkunrẹrẹ alaye si waye lori awọn nkan ti o dara pupọ lati jina si ni asiko ti a ba fẹ jẹ tabi mu.
- Yoruba Oludanileko : Abdur Rahman Muhammadul Awwal Sise atunyewo : Hamid Yusuf
Idanilẹkọ ti o se alaye: (1) Idajọ ẹran ti Musulumi ba pa, yala o da orukọ Ọlọhun si ni tabi ko da orukọ Ọlọhun si ni latari igbagbe. (2) Idajọ Ẹran ti Yahudi tabi Nasara ba pa yala fun ọdun ni tabi fun nkan miran. (3) Idajọ gbogbo ẹran ti wọn ba pa laida orukọ Ọlọhun sii.
- Yoruba Oludanileko : Abdur Rahman Muhammadul Awwal Sise atunyewo : Hamid Yusuf
1- Alaye waye ni agbegbe yii lori itan ranpẹ nipa ẹni tii se iya-iya Anọbi Isa ati iya rẹ pẹlu alaye nipa bi bibi rẹ se waye. 2- Ọrọ waye ni abala yii nipa awọn isẹ iyanu ti Ọlọhun se lati ọwọ Anọbi Isa. Ibeere si waye wipe se ọmọ Ọlọhun ni Anọbi Isa bi? 3- Idanilẹkọ ni agbegbe yii pese idahun si awọn ibeere wọnyii: - Njẹ Anọbi Isa ku ati wipe nibo ni o ku si? - Njẹ Anọbi Isa npada bọ wa si aye, ati wipe igba wo ni? - Ki ni yoo sẹlẹ ni asiko pipadabọọ rẹ? - Awọn ẹri ti o da lori pipadabọọ rẹ.
- Yoruba Oludanileko : Abdur Rahman Muhammadul Awwal Sise atunyewo : Hamid Yusuf
Idanilẹkọ yii da lori awọn Isẹ ti ẹsan wọn maa nbe gbere lẹyin iku pẹlu apejuwe lati inu ẹgbawa hadisi.
- Yoruba Oludanileko : Abdur Rahman Muhammadul Awwal Sise atunyewo : Hamid Yusuf
Alaye nipa ipo Saka yiyọ ninu ẹsin Islam ati awọn anfaani ti o wa nibi yiyọ rẹ yala ni abala ẹsin ni tabi abala iwa.