- Al-Quraani Alaponle
- Sunna
- Ìmọ̀ Akiida
- Ìmọ̀ Taohiid àti ìpín rẹ
- Ìjọsìn ati ìran rẹ̀
- Islam
- Ìgbàgbọ́ ati awọn origun rẹ̀
- Àwọn ọrọ nípa ìgbàgbọ́
- Ṣíṣe dáadáa
- Ṣíṣe aigbagbọ
- Ìwà munaafiki
- Ẹbọ àti ewu rẹ̀
- Àwọn adadaalẹ ati ìran wọn àti àpèjúwe wọn
- Àwọn sàábé ati awọn aráalé anọbi Muhammad
- Wíwá àtẹ̀gùn
- Jijẹ wòlíì ati awọn iṣẹ ìyanu àwọn wòlíì
- Àwọn alujannu
- Ìsòtítọ́ àti ìbọ́pá-bọ́sẹ̀ ati awọn ìdájọ́ rẹ.
- Àwọn ahlus sunna wal jamaa'at
- Àwọn ẹ̀sìn
- Àwọn ẹgbẹ́
- Àwọn ẹgbẹ́ inú Islam
- Àwọn ọ̀nà ìròrí ayé òde òní
- Agbọye ẹsin
- Àwọn ìjọsìn
- Imọra ati awọn idajọ rẹ
- Irun
- Òkú
- Sàká
- Aawẹ
- Hajj ati Umra
- Àwọn idajọ khutuba Jímọ̀
- Irun aláìsàn
- Irun arìnrìn-àjò
- Irun ìpayà
- Biba ara ẹni lo
- Ìbúra àti ìlérí
- Ẹbí
- Ìgbéyàwó
- Kíkọ obìnrin
- Kíkọ obìnrin tí ó bá sunna mu ati Kíkọ obìnrin ti ko ba sunna mu
- Kíkọ obìnrin ti a lè gbà padà ati èyí tí a o lè gbà padà
- Àsìkò tí obìnrin ti òun àti ọkọ rẹ pínyà fi máa kóra ró
- Kí ọkọ àti ìyàwó jọ gbé ara wọn ṣẹ́ èpè
- Fifi ẹ̀yìn ìyàwó ẹni wé ti ìyá ẹni
- Bibura pe eeyan ko nii sunmọ ìyàwó rẹ̀
- Kí ìyàwó kọ ọkọ silẹ
- Gbígba obìnrin tí a kọ̀ padà
- Fífún lọ́yàn
- Títọ́jú
- Ìnáwó
- Aṣọ àti ọ̀ṣọ́
- Fàájì àti àríyá
- Àwùjọ Musulumi
- Ọrọ tí ó jẹ mọ́ ọ̀dọ́
- Ọrọ nipa àwọn obìnrin
- Ọrọ tí ó jẹ mọ́ ọmọdé
- Ìwòsàn àti lílo oògùn àti rukiya ti o bá sheria mu
- Àwọn oúnjẹ ati awọn nǹkan mímu
- Dídá ọ̀ràn
- Ìdájọ́
- Jijagun ẹ̀sìn
- Agbọye awọn àlámọ̀rí tuntun ti o ṣẹ̀ṣẹ̀ ṣẹlẹ̀ ti o n bukata si idajọ ẹsin
- Agbọye ẹ̀sìn àwọn to kéré jù
- Òṣèlú ti shẹria
- Awọn ojú ìwòye nípa agbọye ẹ̀sìn
- Fatawa
- Awọn ipilẹ (ìlànà) agbọye ẹsin.
- Àwọn tira agbọye ẹsin
- Àwọn ìjọsìn
- Awọn iwa rere
- Ede Larubawa
- Pipepe sínú Islam
- Ohun ti o jẹ dandan fun Musulumi
- Awọn ọrọ ti maa n jẹ ki ọkàn ó rọ̀ àti àwọn wáàsí.
- Pipaṣẹ dáadáa ati kikọ kuro nibi ibajẹ.
- Ipò ti pipepe si ti Ọlọhun wa
Muhammad ojiṣẹ Ọlọhun ni
Onka awon ohun amulo: 6
- Yoruba Oludanileko : Abdur Rahman Muhammadul Awwal Sise atunyewo : Hamid Yusuf
1- Alaye nipa aayah Alukuraani ti o wa lori asalaatu sise fun Anọbi [Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki o maa ba a], pataki asalaatu ati wipe bawo ni o se yẹ ki a maa se. 2- Pataki sise asalaatu fun Anabi [Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki o maa ba a] ni ọjọ Jimọh ati anfaani ti o wa nibẹ.
- Yoruba Oludanileko : Abdur Rahman Muhammadul Awwal Sise atunyewo : Hamid Yusuf
Ojuse awa Musulumi si Anabi wa Muhammad [Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki o maa ba a] da lori awọn koko wọnyii: 1. Titẹle asẹ rẹ. 2. Gbigba ọrọ rẹ gbọ ni ododo. 3. Kikọse rẹ ninu iwa, ẹsin ati isesi. 4. Ninifẹ rẹ pẹlu mimaa se asalaatu fun un, ati didaabo bo Sunnah rẹ.
- Yoruba Oludanileko : Abdur Rahman Muhammadul Awwal Sise atunyewo : Hamid Yusuf
Idanilẹkọ yi da lori wipe titẹle asẹ Ọlọhun ati asẹ Ojisẹ Rẹ (ike ati ola Ọlọhun ki o maa ba a) ni ojulowo ẹsin. Alaye si tun waye nipa wipe sise ọjọ ibi Anọbi (Maoludi Nabiyi) ko ba ofin ẹsin Islam mu pelu awọn ẹri.
- Yoruba Oludanileko : Rafiu Adisa Bello Oludanileko : Ishaaq bn Ahmad al Ilaalawi Sise atunyewo : Rafiu Adisa Bello
1- Oro lori koko ohun ti Olohun fi ran ojise Re Muhammad, iranse ni o je si gbogbo aye patapata. 2- Pelu bi o ti je wipe awon osebo fi inira kan ojise Olohun ni ilu Makka sibe sibe o tun fi aanu bawon lo ti ko si fi ibi san ibi. 3- Apejuwe lori aanu ti ojise Olohun ni fun awon eranko. Ikilo si waye lori fifi iya je awon eranko. 4- Apejuwe nipa aanu re si awon ewe tabi awon omode. 5- Apejuwe nipa aanu ojise Olohun si awon obinrin, oro si waye lori bi awon eniyan se maa nse abosi si won ni igba aimokan. 6- Awon apejuwe nipa iteriba ati iwapele ojise Olohun. Bi o ti se ni aanu awon omoleyin re ti awon naa si ni ife si i.
- Yoruba Oludanileko : Abdur Rahman Muhammadul Awwal Sise atunyewo : Hamid Yusuf
Idanilẹkọ yii da lori awọn Iwa Abiyì ti a le kọ ẹkọ rẹ lati ara Anọbi Muhammad [Ikẹ ati ola Ọlọhun ki o maa ba a]
- Yoruba Oludanileko : Isa Akindele Solahudeen Sise atunyewo : Hamid Yusuf
Alaye ohun ti o se okunfa ogun yii ati awon isele ti o waye nibi sise ipalemo fun ogun naa eyi ti o je eri ododo lori wipe Annabi Muhammad ojise Olohun ni. Alaye si tun waye lori aranse ti Olohun se fun ojise Re ninu ogun naa.