108 - Suuratul-Kaothar ()

|

(1) Dájúdájú Àwa fún ọ ní ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ oore.

(2) Nítorí náà, kírun fún Olúwa rẹ, kí o sì gúnran (fún Un).

(3) Dájúdájú, ẹni tó ń bínú rẹ, òun ni kò níí lẹ́yìn.