• Yoruba

  Oludanileko : Qomorudeen Yunus Sise atunyewo : Rafiu Adisa Bello

  Diẹ nipa ete awọn Ijọ Shia fun awa Musulumi ti a wa lori Sunna Anabi wa Muhammad [Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki o maa ba a].

 • Yoruba

  Oludanileko : Qomorudeen Yunus Sise atunyewo : Rafiu Adisa Bello

  Alaye ni ẹkunrẹrẹ nipa adiọkan awọn Ijọ Shia: Adiọkan wọn nipa awọn Saabe Ojise Ọlọhun [Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki o maa ba a], adiọkan wọn si Alukuraani ati bẹẹbẹẹ lọ.

 • Yoruba

  Oludanileko : Qomorudeen Yunus Sise atunyewo : Rafiu Adisa Bello

  Alaye nipa bi Ijọ Shia se bẹrẹ pẹlu itọkasi wipe Yahuudi ni ẹni ti o pilẹ Ijọ Shia.

 • Yoruba

  Oludanileko : Abdur-razaq Abdul-majeed Alaro Sise atunyewo : Rafiu Adisa Bello Sise atunyewo : Hamid Yusuf

  Itumọ aayah kẹtadinlaadọrun lati inu Suuratul Bakọrah eyi ti o da lori iroyin bi Ọlọhun Allah se se aranse fun Anọbi Isa ati bi awọn Yahuudi se tako igbedide Ojise Olohun Muhammad.

 • Yoruba

  Oludanileko : Isa Akindele Solahudeen Sise atunyewo : Rafiu Adisa Bello

  Eleyi ni apa keji ibanisoro naa, olubanisoro nso eyi ti o ku ninu awon majemu ti o ye ki o wa fun eniti a fe fi se olori ninu Islam.

 • Yoruba

  Oludanileko : Isa Akindele Solahudeen Sise atunyewo : Rafiu Adisa Bello

  Waasi yi so nipa bi o ti je wipe esin Islam menu ba gbogbo nkan patapata ti o fi de ibi eko bi a ti se n to tabi ya igbe, bawo ni Islam kose wa ni so nipa eto bi a se ndari ilu ati bi a se nse ijoba.

 • Yoruba

  Oludanileko : Isa Akindele Solahudeen Sise atunyewo : Rafiu Adisa Bello

  Ibanisoro yi da lori idahun fun ibeere ti o n so pe: kinni idi ti Olohun fi da awa erusin Re? Oniwaasi si dahun ni kukuru wipe nitori ijosin ni Olohun fi da awa eniyan ati alijonnu. Oju ona kan soso ti a si fi le sin Olohun naa ni esin Islam.

 • Yoruba

  Oludanileko : Qomorudeen Yunus Sise atunyewo : Rafiu Adisa Bello

  Ibanisoro yi da lori ijosin ati itumo re, oniwaasi so Pataki ki Musulumi se akiyesi awon majemu ijosin mejeeji: awon naa ni sise afomo ise fun Olohun ati sise ise ijosin naa ni ibamu pelu bi ojise Olohun ti se e. Lehinnaa ni o menu baa won oniran iran ijosin gege bii irun kiki aawe saka haj ati beebeelo. Ni ipari o so nipa awon nkan ti o maa nba ijosin je, eyi ti o sit obi ju ninu re naa ni ebo sise pelu Olohun.

 • Yoruba

  Oludanileko : Isa Akindele Solahudeen Sise atunyewo : Rafiu Adisa Bello

  Ibanisoro yi da lori igbagbo ninu Olohun ati alaye itumo re. Olubanisoro yi se alaye pupo lori itumo ohun ti o nje igbagbo, o si fi awon apeere laakaye ba awon eniyan soro pupo nibe nitoripe eleyi ni o ba awon ogooro eniyan ti won wa ni ijoko naa mu. Bakannaa ni o fi awon eri Al-kurani ati hadiisi se alaye.

 • Yoruba

  Oludanileko : Isa Akindele Solahudeen Sise atunyewo : Rafiu Adisa Bello

  Oniwaasi so Pataki esin Islam o si je ki awon eniyan mo wipe gbigba esin Islam kiise mimoose enikan bikose aanu Olohun lori eni naa. Bakannaa o tun so iyato ti o wa laarin Islam ati awon esin yoku, ti o si so awon majemu ti o maa nje ki ise Musulumi di atewogba ni iwaju Olohun. Ni ipari o ba awon ti won gba Islam dupe, o fun won ni iro wipe Olohun maa nfi esin Islam pa awon ese ti eniyan ba ti se koja re, lehinnaa o so fun won bi o ti se je Pataki ki won jinna si ebo sise.

 • Yoruba

  Oludanileko : Abdur-razaq Abdul-majeed Alaro Sise atunyewo : Rafiu Adisa Bello

  Ibanisoro yi je ki a mo Pataki ki Musulumi mo Olohun re ni okan soso ki o si doju ijosin ko Olohun naa. Mimo Olohun ni okan (Taoheed) ni ipile esin, ohun si ni ohun ti o ye ki Musulumi moju to julo.

 • Yoruba

  Oludanileko ninu eto yii soro nipa bi o ti se Pataki fun Musulumi ki o maa tele Sunna Anobi wa Muhammad

 • Yoruba

  Oludanileko : Imran Abdul Majeed Ẹlẹha Sise atunyewo : Rafiu Adisa Bello

  Alaye lẹkunrẹrẹ nipa ibẹru Ọlọhun, awọn ẹri rẹ lati inu Alukuraani ati Sunnah pẹlu apejuwe rẹ ni ọdọ awọn ẹni rere.

 • Yoruba

  Sise atunyewo : Rafiu Adisa Bello

  Awọn ohunatiaworanniede Yoruba pẹluakọle: [Awọn OrukọỌlọhunti O Rẹwajulọni sisẹ n tẹle], niapayiini a tiriOrukọỌlọhun [ Al-Ilah ], pẹlu awọn itumọti O n tọkasi, ọnaakọsilẹ rẹsidaraniriri.

 • Yoruba

  Sise atunyewo : Rafiu Adisa Bello

  Awọn ohunatiaworanniede Yoruba pẹluakọle: [Awọn OrukọỌlọhunti O Rẹwajulọni sisẹ n tẹle], niapayiini a tiriOrukọỌlọhun [ Al-Ahad ], pẹlu awọn itumọti O n tọkasi, ọnaakọsilẹ rẹsidaraniriri.

 • Yoruba

  Sise atunyewo : Rafiu Adisa Bello

  Awọn ohunatiaworanniede Yoruba pẹluakọle: [Awọn OrukọỌlọhunti O Rẹwajulọni sisẹ n tẹle], niapayiini a tiriOrukọỌlọhun [ Al-Waahid ], pẹlu awọn itumọti O n tọkasi, ọnaakọsilẹ rẹsidaraniriri.

 • Yoruba

  Sise atunyewo : Rafiu Adisa Bello

  Awọn ohunatiaworanniede Yoruba pẹluakọle: [Awọn OrukọỌlọhunti O Rẹwajulọni sisẹ n tẹle], niapayiini a tiriOrukọỌlọhun [ As-Sọmad ], pẹlu awọn itumọti O n tọkasi, ọnaakọsilẹ rẹsidaraniriri.

 • Yoruba

  Sise atunyewo : Rafiu Adisa Bello

  Awọn ohunatiaworanniede Yoruba pẹluakọle: [Awọn OrukọỌlọhunti O Rẹwajulọni sisẹ n tẹle], niapayiini a tiriOrukọỌlọhun [ As-Sẹyyid ], pẹlu awọn itumọti O n tọkasi, ọnaakọsilẹ rẹsidaraniriri.

 • Yoruba

  Sise atunyewo : Rafiu Adisa Bello

  Awọn ohunatiaworanniede Yoruba pẹluakọle: [Awọn OrukọỌlọhunti O Rẹwajulọni sisẹ n tẹle], niapayiini a tiriOrukọỌlọhun [ Al-Witr ], pẹlu awọn itumọti O n tọkasi, ọnaakọsilẹ rẹsidaraniriri.

 • Yoruba

  Sise atunyewo : Rafiu Adisa Bello

  Awọn ohunatiaworanniede Yoruba pẹluakọle: [Awọn OrukọỌlọhunti O Rẹwajulọni sisẹ n tẹle], niapayiini a tiriOrukọỌlọhun [ Al-Baatin ], pẹlu awọn itumọti O n tọkasi, ọnaakọsilẹ rẹsidaraniriri.

Oju ewe : 9 - Lati : 1
Irori re je wa logun